Home iroyin Sallah: Ààrẹ Buhari ti lọ Daura fun Sallah.
iroyin - Orisirisi - Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - August 9, 2019

Sallah: Ààrẹ Buhari ti lọ Daura fun Sallah.

 

Aare Muhammadu Buhari ti lo si Daura, ilu re lonii Friday, ati se ayeye sallah ni ojo Sunday.

Oko baalu aare, ti o gbe Aare de Malam Umar Musa Yaradua Airport, ni Katsina ni irole oni ni nnkan bi ago márùn-ún.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…