Home orisiirisii Robbery : ikú ni èrè ẹ̀ṣẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 9, 2019

Robbery : ikú ni èrè ẹ̀ṣẹ̀.

 

Ile ejo ni Ado-Ekiti ti dajo iku fun eeyan meji fun esun pe won jale, ibon ti o to si wa lowo won.

Awon mejeeji naa ni, Sunday Adewa ati Amos Adedayo, won ja arabinrin kan ti n je Abosede Molomo lole ni Ilogbo Ekiti n Ido/ Osi Local Government Area ni ipinle Ekiti ni June 4, 2015.

Adajo ipinle naa, Adajo Ayodeji Daramola, nigba ti o da ejo naa ni ojo Thursday ni, “ mo ri pe e jebi esun ole jija gege bi o se wa ni waju mi, ki won si jiya ese won.

“Fun idi eyi, ile ejo yii pa lase pe ki won so okun mo yin lorun titi emi yoo fi bo lara yin. Ki olorun saaanu emi yin.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…