Home orisiirisii Prostitution : Ìbálòpọ̀ ti gba ẹ̀mí arábìnrin.
orisiirisii - Orisirisi - August 9, 2019

Prostitution : Ìbálòpọ̀ ti gba ẹ̀mí arábìnrin.

 

Awon olopaa ipinle Delta ti mu arakunrin kan, leyin ti o ba onipansaga ti o gbe lopo titi ile fi mo, ti emi si bo lara re.

Awon mejeeji jo sun moju si ile itura ni Amukpe community ni Sapele Local Government Area ni ipinle Delta. Nigba ti okunrin naa gbiyanju ati jade kuro ninu ile itura naa ni awon osise ile itura ri oku arabinrin naa ninaaro ojo Thursday August 8.

Komisona olopaa ipinle Delta, Adeyinka Adeleke, lo fi idi eri isele naa mule, o si ni iwadii si n lo lori nnkan to fa iku naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…