Home orisiirisii Divorce: Iyawo mi fẹ ́fi májèlé pa mí – Arakunrin
orisiirisii - Orisirisi - August 9, 2019

Divorce: Iyawo mi fẹ ́fi májèlé pa mí – Arakunrin

 

Aare Mapo Custimary Court ni Ibadan, Oloye Ademola Odunade ti fi opin si igbeyawo to wa laaarin onisowo kan ti n je Sherif Adesola, ati iyawo re, Damilola, nitori majele ati agbere sise.

Odunade ni igbeyawo to wa laaarin Sherif ati Damilola ti ni iyonu koja atunse.

O si ti ni ki Damilola ma goju omo won omo odun meji, ki Sherif si ma fun Damilola ni egberun márùn-ún losoosu fun itoju omo won.

Sherif so fun ile ejo pe oun fe ipinya nitori Damilola gbiyanju ati fi majele si ounje oun, o ni oun ka nibi ti o ti n fi majele si ounje naa, nigba ti oun si fi ejo re sun awon obi re, won o se nkankan nipa re.

O ni Damilola ma n bu oun, o si ma n fa oun ni aso ya ni gbangba. O ni oun o fe ki Damilola pa oun ki ile jowo tunp awon ka.

Damilola ti o je onidiri ni onisina ni Sherif, o ni o ba ore ni ibasepo, o si fun loyun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…