Home orisiirisii Accident : Arákùnrin ọmọ Nigeria ti kú sínú Ìjàm̀bá ọkọ̀ ní òkè-òku
orisiirisii - Orisirisi - August 9, 2019

Accident : Arákùnrin ọmọ Nigeria ti kú sínú Ìjàm̀bá ọkọ̀ ní òkè-òku

n.

Arakunrin omo odun merinlelogun, ti o je omo Nigeria ti ku sinu ijamba oko ni Cyberjaya, Selangor ni orile-ede Mal, ni aaro ana ojo Thursday.

Ijamba naa sele leyin ti oko re Honda Civic gba igi kan ti o si yipo ni iwaju Cyberjaya National School(SK).

Arakunrin naa ti won ni o n jeMuhammad Saas Yuguda, omo ipinke Gombe, ku loju ese latari bi o se farapa to.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…