Marital vows: Àwọn arúgbó méjì ti ṣe ìgbéyàwó.
Baba odun merindinlogorun ti n je James K. Andorful omo ile Ghana ati ololufe re mama odun metalelaadorun ti n je Margaret Manuel, ti se igbeyawo won ni ojo satideAuhust3.
Awon mejeeji ti jo n gbe fun aadota odun, ti won si bi omo mesan-an fun ra won. PasitoDansoman district ti ile ijosin church of pentecost, Rev. Jamea Oko Banor lo dari igbeyawo naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…