Lagos State Police: wón ká ìbọn ọlọ́pàá lọ́wọ́ arákùnrin.
Won ti ka ibon olopaa lowo arakunrin kan ninu oko ero ni Onitsha ni ipinle Anambra.
Won mu arakunrin naa ti n je Sunday Onyema, omo odun marundinlogoji, ti o je omo ilu Orluni ipinle Imo, ni agbegbe Upper Iweka ni Onitsha.
Won ni o n bo lati Asaba, ipinle Delta, ninu oko eronigba ti awon olopaa da oko won duro lati se ayewo, won si ba ibon olopaa ti nomba re je AO-4909Z ti ota si wa ninu re.
Agbenuso awon olopaa ipinle naa, Haruna Mohammed, lo fi idi eri isele naa mule.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…