Kidnapping : lọ́yà ti gba bàbá rẹ̀ sílè lọ́wọ́ àwọn ajínigbé.
Loya kannti fi aworan bi o se farapa to nibi ti o ti n gbiyanju ati gba baba re ti n saare sile lowo awon ajinigbe ni ile won ni Aba ni ipinle Abia lojo Wednesday August 7.
Loya naa ti n je @ChrisEcia lori Twitter so pe, awon ajinigbe naa ro pe elegbe okunkun ni oun, awon idi ti won fi wa ni lati ji baba oun gbe, amo oun o fun won ni aaye nitori oun ba won ja.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…