Home orisiirisii Trailer Accident: Ìjàm̀bá ọkọ̀ tí gba ẹ̀mí èèyàn méjì.
orisiirisii - Orisirisi - August 7, 2019

Trailer Accident: Ìjàm̀bá ọkọ̀ tí gba ẹ̀mí èèyàn méjì.

 

Ijamba oko trailer ati okada ti gba emi eeyan meji, eyi waye leyin ti trailer naa gun eni ti n wa okada naa ati obinrin ti o gbe,o si run won ni titi Otukpo ni Markurdi, ipinle Benue.

Ijamba naa waye nj ago mejo koja isegun ogoji aaro oni, awon mejeeji ni won si ku loju ese.

Adari Federal Road Safety Commission (FRSC) ni agbegbe naa, Aliyu Baba lo fi idi eri isele naa mule, o si ni won ti fa dirafa oko trailer naa le awon olopaa lowo.

Awon osise FRSC si lo si ibi ti ijamba naa ti waye lati ko eerun ara awon ti ijamba naa sele si sinu ora nylon, won si gbiyanju lati yanju goslow.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…