Taskforce: àwọn òṣìṣẹ́ task force ti gé irun àwọn ọkùnrin.
Awon osise taskforce ti fi ipa ge irun awon okunrin ni Kontagora, ipinle Niger ojo Monday, August 5.
Gege bi iroyin Hausa media Platform, Rariya, se so, won fi esun kan awon okunrin naa pe won n gbe irun ti to to. Awon oise taskforce naa si fi scissors ge irun won.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…