Home iroyin Seyi Makinde: Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti mú ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ ni pàtàkì.

Seyi Makinde: Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti mú ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ ni pàtàkì.

 

Gomina ipinle Oyo, Seyi Makinde, ti fi owo si pe ki won ma san egberun naura lonaneedegbeta(500 thousand naira) fun awon omo Oyo ti won je akekoo ni ile iwe ofin.

Gomina naa se ipolongo yii nigba ti o gba lara awon omo Oyo ti wonnwa ni ile iwe ofin ni alejo ni ofisi re. Gege bi gomina naa se so, won se ipinu naa lati le maa se koriya fun awon akekoo ki won le ma se daadaa ni ile iwe won, ki won si mu ni pataki.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…