Home iroyin President Buhari: Ààrẹ Buhari yoo ṣe ìbúra fún àwọn minisita tuntun.

President Buhari: Ààrẹ Buhari yoo ṣe ìbúra fún àwọn minisita tuntun.

 

Aare Buhari yoo se ibura fun awon minisita tuntun ni ojo Wednesday, August 21, 2019.

Akowe, Cabinet Affairs Office of the Seceto the Government Federation, Babatunde lawal, lo je ki o di mimo ninu gbolohun ti o fi kale.

Ni ose ti o koja ni National Assembly pari ayewo fun awon metalelogoji ti won yan fun ipo minisita.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…