Gang clash: wón ti yin ìbọn pa gírádúátì.
Won ti yin ibon pa giraduati Cross River University of Technology (CRUTECH), Isaac Atamba, nitori wahala laaarin egbe to waye ni Calabar.
Atamba je of ilu Igwo ni Obudu LGA ni ipinle Cross River, won yin inon pa a ni ojo Friday, August 2, ni soobu re nibi ti o ti n sise alagbafo ni Atimbo, Calabar Municipal.
Ki olorun te emi re si afefe ire.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…