Home iroyin Bank Robbery: àwọn olè ti gba ẹ̀mí èèyàn méjì.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 7, 2019

Bank Robbery: àwọn olè ti gba ẹ̀mí èèyàn méjì.

A gbo pe awon ole ti gba emi eeyan meji nigba ti won lo jale ni ile ifowopamo Wema Bank ni Iju-Itaogbolu, ni Akure north local council are ni ipinle Ondo.

Gege bi iroyin se so, awon ole ti won wo ilu naa to mejo, won si pin ara won si meji ki won to bere ise ibi won. Eni ti isele naa soju re ni won mu awon ara ilu naa ni idogo fun igba pipe, ti won si n yin ibon lopolopo igba. Lara awon osise naa ati onibara won farapa.

Komisona olopaa ni ipinle Ondo, Undie Adie, lo fi idi eri isele naa mule, Wema Bank naa fi idi eri isele naa mule, won si ni won ti ke pe awon ti o ye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…