Yahoo Boy: Wọ́n ti mú ọkùnrin oníjìbìtì.
Economic and Financial Crimes Commission EFCC ti mu arakunrin omo odun merinlelogun ti n je Victor Idahosa, leyin ti won fura si pe onijibiti ni(yahoo boy).
Eni ti won fura si naa je omo ipinle Edo, won mu ni Cristolyte Close Diamond Estate ni Lekki-Ajah ni ipinle Eko. Won gba oko kan, ero ayabiasa(apple laptop) meji, email onijibiti, oogun ati awon iwe onijibiti lowo re.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…