Home orisiirisii Toke Makinwa: mo ti ṣe tán láti ṣe ìgbéyàwó ni ìgbà kejì.
orisiirisii - Orisirisi - August 6, 2019

Toke Makinwa: mo ti ṣe tán láti ṣe ìgbéyàwó ni ìgbà kejì.

 

Gbajumo onkowyati osise ori redio, Toke Makinwa ti ni oun ti setan lati se igbeyawo ni igba keji ati lati bimo nitori oun ma pe omo oudn marundinlogoji ni November odun ti a wa yii.

Igbeyawo Toke akoko daru leyin ti oko re fun obinrin loyun. Won se igbeyawo naa ni January 2014, won si fi opin si ni October 2017 ni ile ejo.

Toke ti so lori instagram pe odun yii ni o ma dopin ti oun ma a je obinrin ti ko ni oko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…