Home orisiirisii NYSC: Àwọn agbèrò ti gún Àgùnbánirọ̀ àti ọlọ́pàá.
orisiirisii - Orisirisi - August 6, 2019

NYSC: Àwọn agbèrò ti gún Àgùnbánirọ̀ àti ọlọ́pàá.

Awon agbero ti gun agunbaniro ati olopaa ni agbegbe Alfa Yaya ni Ilroin, ipinle Kwara.

Gege ni iroyin se so, o ku die ki olopaa naa padanu oju kan, agunbaniro naa si padanu eje pupo.

Awon mejeeji wa ni ile iwosan, won si m gba itoju lowo lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…