Home orisiirisii Murder: wón rí òkú arábìnrin ní abé ibùsùn ní ilé ìtura.
orisiirisii - Orisirisi - August 6, 2019

Murder: wón rí òkú arábìnrin ní abé ibùsùn ní ilé ìtura.

 

Won ri oku arabirin ni abe ibusun ni ile itura kan ni Owerri, ipinle Imo.

Eni ti isele naa soju re ni isele naa waye ni opin ose ti o koja ni ile itura kan ti o gbajumo ni titi World Bank ni Owerri, won ni afole ni o ri oku naa. Won ni o soro lati da arabinrin naa mo nitorieni ti o pa a ti ko gbogno nnkan re ti won le fi damo lo.

Awon olopaa ipinle Imo ti n se iwadii lori isele naa, won si fura pe oogun owo ni won fi se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…