Lagos State Police: Wọn ti pa ọlọ́pàá.
Awon apaniyan ti pa olopaa kan ti o wa ni Isua-Akoko police division ni ipinle Ondo.
Isele naa waye ni ojo Monday, August 5 nigba ti ofisa naa ati ofisa miiran n sise ni titi ti o lo si ipinle Ondo, Edo ati Kogi. Won yinbo fun ti o si ku, amo ofisa keji salo.
Agbenuso awon olopaa ipinle Ondo lo fi idi eri isele naa mule fun Channels Telivision.
O so pe iwadii ti n lo lori isele naa lati mu awon ti won sise ibi naa,, ati daabobo emi ati oun ini awon ti n gbe ni agbegbe naa. Won mo titi naa fun ise ibi ajinigbe, ole jija ati awon iwa odaran miiran.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…