Home orisiirisii Sniper : Arákùnrin ti fi òògùn p’ẹ̀fọn gba ẹ̀mí ara rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 5, 2019

Sniper : Arákùnrin ti fi òògùn p’ẹ̀fọn gba ẹ̀mí ara rẹ̀.

 

Arakunrin omo odun marundinlogoji ti gba emi ara re ni agbegb Ijanikin ni ipinle Eko.

Gege bi a se gbo, awon olopaa ago olopaa Ijanikin gba ipe ijaya ni ojo Satide, August 3 pe arakunrin ti ko si emi lara re mo wa ninu igbo kan legbe afara ti Adio bus stop ni agbegbe Ijanikin.

Awon ti n se ayewo ati awon olopaa si lo si ibe lati se ayewo.

Nigba ti won se ayewo, won ri ike Sniper legbe okunrin naa, ti won si lero pe oun lo mu un. Awon olopaa ni won oku naa lo si ile iwe Mainland General Hospital ni Yaba lati se ayewo.

Iwadii si n lo lori isele naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…