Home orisiirisii Murder: Arákùnrin ti pa àbúrò ìyàwó rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 5, 2019

Murder: Arákùnrin ti pa àbúrò ìyàwó rẹ̀.

Isele buruku kan ti waye ni agbegbe Sapele ni ipinle Delta, leyin ti arakunrin kan pa aburo iyawo re nitori o n gbeja egbon re ti o n se isina.

Arabinrin naa ti jewo pe oun ba egbon oko re ti n je Pius ni ibasepo, eyi si fa wahala laaarin oko re ati aburo re. Oko naa si fi ibinu lo mu ibon, o si yin si oju osi aburo iyawo re, eyi si fa iku arakunrin naa.

A gbo pe awon ebi oko naa dana sun ile oloogbe naa, leyin ti awon ebi iyawo ti dana sun ile Pius. Awon olopaa ipinle Delta ni won fi idi eri isele naa mule, won si won ti n wa oko naa ti sa lo leyin ti isele naa waye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…