Home orisiirisii Mi ò kábàmọ́ọ̀ pé mo pa bàbá mi – arákùnrin ọdún ogójì.
orisiirisii - Orisirisi - August 5, 2019

Mi ò kábàmọ́ọ̀ pé mo pa bàbá mi – arákùnrin ọdún ogójì.

 

Arakunrin omo odun ogoji ti n je Bisso Aminu, ti ni oun o kabamoo pe oun pa baba re omo odun marundinlaadorin, Aminu Allahbani. Gege bi Bisso se so, o ni baba oun wa ninu egbe okunkun pe ti oun o ba pa a, o ma pa oun.

Awon olopaa ipinle Niger ni won lo gbe Aminu, leyin ti o fi oko sa baba re lati oju orun.

Nipgba ti Aminu n ba awon oniroyin soro, o ni oun o kabamoo nnkan ti oun se, oun si ti setan lati dojuko nnkan ti o ba ma sele.

Agbenusoawon olopaa ipinle naa, DSP Muhammad Abubakar, lo fi idi eri isele naa mule, o si ni leyin ti wonba pari iwadii, arakunrin naa yoo fi oju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…