Home orisiirisii Lagos Stories: Wọ́n ti rí òkú arákùnrin kan nínú ọkọ̀ rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 5, 2019

Lagos Stories: Wọ́n ti rí òkú arákùnrin kan nínú ọkọ̀ rẹ̀.

 

Won ti ri oku arákùnrin omo odun mokanlelogota ti n je Adebekun Olusegun Samuel ninu oko re ni titi Obalende ni Isale Eko.

Agbenuso awon olopaa ipimle Eko, Bala Elkana, won gbo ipe ijaya ni ago olopaa ni Onikan, lati Obalande pe arakunrim kan ti ara mo inu oko re, Toyota Camry ti nomba re je BEN 231 CB, awo Gold.

Leselese won lo si ibe, won si fi ipa se ilekun oko naa, won si ri oe arakunrin naa ti gbe emi mi.

Bala ni; won tete pe awon molebi re pelu ago re. Won si so oruko arakunrin naa fun won pe Adebekun Olusegun Samuel ni oruko re, pe omo odun mokanlelogota ni, pe o ti se aare tele, eyi si fi han pe ki so madaru ninu isele naa.”

O fi han pe won ti fa oku ati oko re le awon molebi re lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…