Lagos State Police: Olopaa kan ti bá obìnrin sùn láìsan owo fun.
A gbo pe olopaa ipinle Eko kan ti ri ete leyin ti o ba obinrin onipansaga kan ni ibasepo ti ko si san owow re fun. Arabunrin nee si yeye olopaa naa ni isoju awon eeeyan ni agbegbe Idasho ni Ibeju Lekki.
A gbo pe adehun won pe olopaa naa ma san egebrun naura meje fun arabinrin naa ti o ba sun ti titi ile fi ma mo. Amo nigba ti ile mo, olopaa naa ko egebrun naira merin le obinrin naa lowo, eyi lo si fa wahala.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…