Home ÀKỌ̀TUN Soyinka, Falana àti Ozekhome lòdì sí àtìmó̩lé Sowore̩
ÀKỌ̀TUN - orisiirisii - Orisirisi - August 4, 2019

Soyinka, Falana àti Ozekhome lòdì sí àtìmó̩lé Sowore̩

Ojogbon Wole Soyinka, Agbejoro agba Femi Falana ati Mike Ozekhome ni iyanje patapata gbaa ni bi ajo awon olopaa inu se lo fi owo sinkun ofin mu Ogbeni Omoyele Sowore.
Sowore ni o wa pelu awon oludije du ipo Aare ninu osu keji odun yii sugbon ti kadara ko see loore lati wole ibo naa.
Sowore yii kan naa ni oludasile iroyin ori ero ayelujara kan “Sahara”.
Ohun Kan yii naa ni won ni o n se agbateru bi iwode lori aabo orileede yii to mehe se maa dopin ni ojo karun-un Ola yii. Ajo DSS ni eyi lo faa ti awon se fi owo sinkun ofin muu. Ajo yii ni “oloju ko ni laju re sile ki talubo ko sii”.
Won ni “ibere ija ni eniyan le mo, ko si eni to le mo ipari re”.
Eyi naa lo faa ti awon ojogbon ,omowe pelu awon agbejoro lolokan-o- jokan se n benu ate lu ijoba lori oro naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…