Home orisiirisii Wọ́n ti gbé Omoyele Sowore.

Wọ́n ti gbé Omoyele Sowore.

Awon osise Departnent of State Security, DSS, ti gbe atew ati olidati Sahara Reporters, Omoyele Sowore.

Gege bi Sahara Reporters se so, won gbe Omoyele ni aaro oni Satide August 3, ni ile re, won gbe oko merin wa, won si gba foonu ati awon nnkan ini re lowo re, won o ti mo ibi ti won gbe lo.

Sowore ko o si ori twitter ni ago kan koja iseju marundinlogun pe “DSS invades Sowore’s”. Eyi ni pe DSS ti wa si ile Sowore. Eni kan ti isele naa waye loju re ni won fi agifi gba foonu Sowore.

Sowore je okan lara awon ti dije fun ipo aare labe egbe oloselu Africa Action Congress, ni ibo 2019 ti o koja.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…