Home orisiirisii Àwọn ará Ikorodu ti gba ọkàn lára wọn sílẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 3, 2019

Àwọn ará Ikorodu ti gba ọkàn lára wọn sílẹ̀.

Awon ara Ikorodu ti pejo si ori awon Special Anti-Robbery Squard (SARS) leyin ti won gbiyanju ati mu arakunrin kan.

A gbo pe awon SARS naa gbiyanju ati mu okunrin ti won fi esun onijibiti(yahoo yahoo) kan. Awon ara adugbo naa si gbiyanju ati gbe arakunrin naa, won si pariwo ole le won, awon ofisa naa si ko wo oko won, won si sa lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…