Home orisiirisii Àwọn agbófinró ni South Africa tí mú ọmọ Nigeria.
orisiirisii - Orisirisi - August 3, 2019

Àwọn agbófinró ni South Africa tí mú ọmọ Nigeria.

Arakunrin omo Nigeria kan ti fi oju ba ile ejo ni ojo Tuesday ni Welkom Magistrate’s Vourth ni South Africa fun eaun oogun lile, leyin ti won mu ni Welkom CBD ni aaro ojo Monday.

Awon ara Welkom POP Reaction Team n se ayewo oko, eyi ti o je ise tiwon, nigba ti won ri oko Toyota Tazz ti gbogbo gilasa re dudu pelu okunrin meta ninu re, eyi si mu ifura dani.

Won da oko naa duro, won si se ayewo re ati awon ti won wa ninu re, won si ri oogun lile pelu owo ninu re.

Won si mu arakunrin omo odun mokanlelogbon naa, won si gbe lo si ago olopaa Welkom.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…