Home orisiirisii Akẹ́kọ̀ọ́ Yunifásítì tí Ìbàdàn ti kú.
orisiirisii - Orisirisi - August 3, 2019

Akẹ́kọ̀ọ́ Yunifásítì tí Ìbàdàn ti kú.

Akẹ́kọ̀ọ́ Yunifásítì tí Ìbàdàn ti kú.

Akekoo olodun kerin ni Yunifasiti ti Ibadan, Victor Ajidagba ti ku ni ale ojo Wednesday.

Ajidagba, ti o je akekoo ni eka nosin, ku si University College Hospital (UCH), ti inu ogba ile iwe.

Iroyin ni, akekoo na n rin ni ala ti eka Physiology nigba ti o subu lule ni ago márùn-ún koja isegun ogun ale, ki awon akekoo meji to gbe lo si ile iwosan ile iwe naa, Jaja, nibi ti o ku si.

Adari Public Communication, Ogbeni Olatunji Oladejo, lo fi idi eri isele naa mule, o si ni, won ko le so oun to fa iku re, amo ile iwe naa ma se iwadii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…