Home iroyin Ìyá ti da omi gbóná lu ọmọ rẹ̀.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - August 2, 2019

Ìyá ti da omi gbóná lu ọmọ rẹ̀.

Arabinrin kan ti o da omi gbona ku omo re obinrin odun metala, ni agbegbe Ilupeju ni ipimle Eko ni ojo Tuesday, July 30 ti ni ise esu ni.

Arabinrin naa ti n je Mrs Davies, fi esun ole kan omo re David Glory pe o ji ogorun naira marun. Nigba ti o n bere oro lowo omo naa, o ni oun mo nnkankan nipa re, o si gbiyanju lati rin kuro niwaju mama re, ni Mrs David ba gbe omi gbon lori ina o si da a lu omo re.

Eyi fa ipalara fun Glory, won si ti gbe lo si ile iwosan Gbagada nibi ti o ti n gba itoju lowo.

Ajafetoo,Harrison Gwamnishu ti ni Mrs David ti wa ni ago olopaa, o si ma fi oju ba ile ejo ni aaro oni, 2 August, 2019.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…