Home iroyin Ìgbìmò tí Saraki darí ti d’ínà ìjẹ́rìí Magu nítorí àṣepamọ wọn – Alaafin Oyo.

Ìgbìmò tí Saraki darí ti d’ínà ìjẹ́rìí Magu nítorí àṣepamọ wọn – Alaafin Oyo.

Alaaafin Oyo Oba Lamidi Adeyemi III, ni ojo Thursday August 1 ti fi esun kan igbimo ti Saraki dari pe won dina ijerii Ibrahim Magu gege bi Alaga Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) nitori ohun ikoko ti won se pamo.

Alaafin so eyi nigba ti o se ipade pelu igbimo ti olori Ibadan Zonal Head of Commission, Friday Ebelo. Alaafin ni oun to fa eyi ni fun Ibrahim Magu ni gbogbo owo ti won ji ti won si gba pada.

O ni:

“Igbimo National Assembly kejo ti gbiyanju,won sa gbogbo agbara won lati ri pe Ibrahim Magu o wole. Kilode? Se nitori won ni asepamo ni,”

“A gbodo gba e niyanju. A gbodo ti e leyin, ki a s i fowosowopo pelu e, aijebe ibaje yoo pa Nigeria.

“Iberu EFCC n sun awon ti n jale yii lo si aimoye ibi ni agbaye. Awon o n le won. O n mu won. Ko si ibi ti won le sa pamo si.

“Latara e, mo fe gboriyin fun Ibrahim Magu fun ise ribiribi.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…