Home orisiirisii Femi Otedola ń ṣayẹyẹ ọjọ́ ìbí ìyàwó rẹ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 2, 2019

Femi Otedola ń ṣayẹyẹ ọjọ́ ìbí ìyàwó rẹ̀.

 

Nana Otedola, iyawo onisowo bilionu, Femi Otedola, ti o je omo ile Ghana, ti pe omo odun mokandinlaadota, lonii, August 2, 2019.

Oko re lo gbe aworan iyawo re si ori afefe, o si ko: “iyawo olojo ibi, iya dada, awon omo dada…F.Ote”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…