Home orisiirisii Àwọn olè ti pa Àgùnbánirọ̀.
orisiirisii - Orisirisi - August 2, 2019

Àwọn olè ti pa Àgùnbánirọ̀.

 

Awon ole ti pa arakunfin kan ti n je Alenin Joseph, girifuati Ambrose Alli University Ekpoma. Won jun ni obe, won si gba foonu re nigba ti o n pada lo si Warri lati Calabar, nibi ti o ti lo sin ile baba re.

Joseph parí agunbaniro e ni July 25 ni Calabar, ipinle Cross River.

Ni ojo Saturday, July 27, nigba ti Joseph n lo si ile ni Warri, ipinle Delta. O wolu ni ale, o si n lo si ile nigba ti awon ole naa da lona, o da okan lara won mo, ti n je Buchi (Omo mama Onome), nitori naa, won gun titi emi fi bo lara re.

Gege bi nnkan ti awon ore re so ni ori Facebook,won ni awon ti won fura si naa tun gbiyanju lati ja elomii lole ni ojo Sunday, July 28, ki owo to te won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…