Home iroyin Mo ní gbogbo fígọ̀ ìbò ọdún 2019 – Aare Buhari.

Mo ní gbogbo fígọ̀ ìbò ọdún 2019 – Aare Buhari.

 

Aare Buhari ti fi han pe oun ni gbogbo figo ibo 2019 nigba ti o gba Olu of Warei, Ololajulo Ogiame Ikenwoli ni alejo ni ile ilu ni Abuja.

Aare si ti fihan pe won ti gbe igbese lati yanju awon wahala lori oro abo ni orile-ede, o si ti ni oun maa ri pe won pari awon ise ti n lo lowo. Gege bi o se so, o ninoun mo ipa ti o le ko ninu igbesi aye ninu awujo.

Nigba ti o ma fesi si atileyin awon Itsekiri ni ibo 2019, Aare ni oun dupe lowo won, o si ni ‘ mo ni gbogbi figo ibo 2019, mo si mo ipa ti awon Itsekiri ko’.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…