Kámẹ́rà ti gbé olè níbi tí ó tí ń jalè.
Kamera CCTV ti gbe awon ole kan nibi ti won ti ji eru enikan ninu oko re. Gege bi a se gbo, isele naa waye ni ojo Tuesday, July 30.
Awon ti won n soro ninu fideo naani awon ole naa po iyo ati ito papo lati fi fo gilasi oko naa, ti won si raye wo oko naa lati jale.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…