Ìjàm̀bá ọkọ̀ ojú omi ti gba ẹ̀mí àwọn èèyàn.
Ijamba oko oju omi ti gba emi eeyan marundinlogun, ti won o si ri opo eeyan ni Borgu Local Government Area ni ipinle Niger.
Won ti awin eeyan n bo láti oja Warrah, ni Ngaski Local Government Area ni ipinle Kebbi si Sabo Yjmu ni Borgu, nigba ti isele naa waye ni irole Sunday.
Gege bj a se gbo, won ni o se e se ki o je pe oju ojo ti o da to lo fa a ti oko oju omi naa se kolu igi ti o si fa ijamba naa.
A gbo pe won ti ri oku marundinlogun, won si ti ran awon meji lowo, won o si ri awon eeyan to ku. Amo won si n wa won.
Ki olorun te emi awon oloogbe naa si afefe ire.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…