Home orisiirisii Bàbá ti dún ọmọ rẹ̀ obìnrin l’ọ́rùn.
orisiirisii - Orisirisi - August 1, 2019

Bàbá ti dún ọmọ rẹ̀ obìnrin l’ọ́rùn.

 

Awon olopaa ipinle Adamawa ti gbe arakunrin kan ti n je Ogbeni. Seidu Dan Iya fun esun pe o dun omo re lorun.

Won ni arakunrin naa ni aarun opolopo leyin asilo oogun ojo pipe, awon ara ile won lo pe olopaa si i, ti won si gbe lo si ago won. Nigba ti won bere pe kilode ti o fi wu iwa naa, o ni o ko wun oun lati dun omo oun lorun.

Agbenuso olopaa ipinle naa, Suleiman Yahaya, lo fi idi eri isele naa mule, o si ni iwadii ti n lo lori ilera arakunrin naa.

Dr. Elkanah Patrick ti n toju omo odun mejo naa, Zarau Seidu ti ni owo olorun ninemi omo naa wa, pe o se e se ki o ye tabi ki o ma ye. Dr. Yerima Suleiman ti ni won wa toju omo naa ni ofe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…