Home orisiirisii Wọ́n ti mú ọkùnrin mẹ́ta fún olè jíjà.
orisiirisii - Orisirisi - July 26, 2019

Wọ́n ti mú ọkùnrin mẹ́ta fún olè jíjà.

Awon olopaa ipinle Niger ti mu okunrin meta yi fun esun pe won lowo si ole jija ti n waye ni osu die seyin ni agbegbe Rafi.

Awon ti won fura si ti won mu ni titi Maikujeri-Kagara ni Rafi Local Government Area ti ipinle naa ni Usman Alhassan, omo odun ogbon, Haliru Usman, omo odun metadinlogbon ati Sani Idi, omo odun metadinlogbon, gbogbo won je omo ilu Maikujeri.

PRO olopaa ipinle naa lo fi idi eri isele naa mule, o si ni awon eni ti won fura si naa ti jewo esun naa. O ni won ka ibon Ak-47 ti won ro lowo won ati ota ibon.

O ni won a to fi oju ba ile ejo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…