Home orisiirisii Omi ti gbé akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlá lọ.
orisiirisii - Orisirisi - July 26, 2019

Omi ti gbé akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlá lọ.

Omi ti gbe akekoo omo odun metala, Egbadon Overcome, lo.

Overcome je omo olodun keta ni ile iwe primary Idumu Ague ni Uromi, Esan North East Local Government Area ni ipinle Ondo.

Awon eeyan ti isele naa waye loju won ni ojo ti o ro lo fa agbara.

Awon osise Federal Road Safety Corps ni won ri oku omo naa.

Alaga Edo State Universal Basic Education Board, Dr Joan Oviawe ni oun ti ran awon eeyan lo lati se iwadii oun to fa isele naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…