Home iroyin Ejò j’ábọ́ láti orí àjà ní House of Assembly.

Ejò j’ábọ́ láti orí àjà ní House of Assembly.

Isele kayefi kan ti waye ni osan ana July 25 ni House of Assembly ti ipinle Ondo leyin ti ejo kan sadede jabo lati ori aja nigba ti won n se ipade.

Isele naa mu ki awon omo egbe sa asala fun emi won, ti o si da ipade ti ojo Thursday ru.

Ejo naa salo mo won lowo, fun idi eyi, won ma dawo ise duro titi digba ti won ma fi tun ile naa se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…