Home orisiirisii E wo ejò l’ọ́rùn obìnrin.
orisiirisii - Orisirisi - July 26, 2019

E wo ejò l’ọ́rùn obìnrin.

Osere Nollywood, Uche Ogbodo ti gbe fideo ara re kan nibi ti o ti we ejo nla kan sorun fun ere kan.

Ogbodo n se ere Omo Ejo ninu ere naa, o ni “ejo mi re e, ko tii ma gboro si mi lenu, ko tii da mi mo daadaa, mo n se ere Omo Ejo AZUMMIRI ninu ere ibile yii.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…