Wọ́n ti gbe arábìnrin tó fi okùn so ọmọ rẹ̀.
Awon figilante ti gba arabinrin kan to fi okun so omo re nitori ko gba ile.
Somto Okafor so lori Facebook pe oun gbe igbe omo ninu ile kan ni Awka, ipinle Anambra. Leyin iwadii, o ri omo obinrin kan ti won fi okun so. O pada di mimo pe mama omo naa ni o fi okun so omo naa.
Eyi fa ibinu pupo, ti awon figilante si gbe iya omo naa.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…