Home orisiirisii Omi ti ya wọ Abuja.

Omi ti ya wọ Abuja.

Ojo nla kan to ro ni aaro oni omo Thursday ti dawo irinse oko duro ni Federal Capitol Territory, Abuja.

Omi ya wo agbegbe Nigerian Army Resource Centre ni Abuja-Zuba expressway, opolopo oko ni o si ha sinu omi naa.

Apa kan ni tit Askkoro naa o se e koja fun awon oko.

Titi to tọ lo si Aso Drive, Department of State Services Headquarters kan geeti Presidential Villa naa o se e gba koja.

Awon ti n bo lati Kubwa ni lati wa onomiran lati gba.

Opolopo soobu ati ibi ise ni won to si titi di ago mokanla aaro.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…