Home orisiirisii Ọlọ́pàá ti gbé ọkùnrin tí ó fọ ìyàwó rẹ̀ létí.
orisiirisii - Orisirisi - July 25, 2019

Ọlọ́pàá ti gbé ọkùnrin tí ó fọ ìyàwó rẹ̀ létí.

Arakunrin kan fo obinrin kan leti ni ita gbangba, nigba ti won si gbiyanju ati bawi, o ni ko si nnkan ti enikeni le se fun oun nitori iyawo oun ni. Amo arakunrin kan ti isele naa waye loju re pe olopaa, won si gba arakunrin naa lo.

Joseph Palmer so lori twitter pe: “ ni ana arakunrin kan fo obinrin ti o wa legbe re leti, inu bi mi, mo si fi olopaa deru ba a. O ni mo to be nitori iyawo oun ni arabinrin naa. Mk pe awin eeyan kan, bi a se n soro yii, o ti wa ni aho llopaa.”

O fikun pe:” inu mi dun pe mo raye fi han awon eeyan pe ija o le yanju wahala nitori gbobbo won n so pe ko kan mi, pe o le arabinrin naa se nnkan to ba wun un, ke de ma wa wo o, loya ni arabinrin naa.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…