Home iroyin Àwòrán láti ìsìnkú Precious Owolabi.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 25, 2019

Àwòrán láti ìsìnkú Precious Owolabi.

Won ti sin oku Precious Owolabi, agunbaniro ti ota ibon da emi re legbodo latari rogbodiyan to waye laaarin awon olopaa ati awon shi’ites ni ojo Monday July 22.

Owolabi ti o ye ki agunbaniro re dopin ni osu meta si igba ta wa yii, ni won sin lonii si Wusasa cemetery Zaria, awon ore, ara, molebi ati awon agunbaniro egbe re ni won pejo sibe, ti win si n sukun.

Ki olorun te emi re si afefe ire.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…