Àwọn SARS sá lọ lẹ́yìn tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ TASUED ya bò wọ́n.
Awon osise Special Anti-Robbery Squard(SARS) ti ri koja nnkan ti won n wa leyin ti won lo si Tai Solarin University of Education lati lo mu akekoo kan fun ese aimodi.
Ninu fideo kan ti won gbe si ori afefe, ni a ti ri awon osise SARS naa nibi ti won ti n sa ti won si fi oko sile leyin ti awon akekoo naa jijangbara. Awon akekoo naa si ba oko ti won fi sile je.
Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.
Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…