Home orisiirisii Àwọn figilanté tí mú àwọn tí wón fura sí bí olè ni Ikorodu.
orisiirisii - Orisirisi - July 25, 2019

Àwọn figilanté tí mú àwọn tí wón fura sí bí olè ni Ikorodu.

Awon egbe figilante ni Ikrodu ni ipinle Eko, ti won n je Onyabo ti mu ti won fura si bi ole ni ago merin aaro ni opin ose ti o koja ni Sabo.

Awon ole ti won fura si yoi ti koko lo ja alufaa musulumi kan, aburo re ati awon kan ni Adaraloye Street ni Ikorodu, ki won to wole to ekun, awon Onyabo, bi won se ri won ni won bere si ni le won nitori omo ti a bi nile ire kii rin irin oru.

Awon ti won fura si naa ni Ogunleye Sodiq, omo odun mokanlogbon, olokada ti o ma n wa won kiri, Abiodun Williams (ti won n pe ni Oki) omo odun marundinlogun ati Lanre Bakare (ti won mo si Sia), omo odun mejidinlogbon.

Eni kerin, Tunde(ti won mo si Oju), ti sa lo leyin ti awon Onyabo le okada won ni Sabo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…