Home orisiirisii Arábìnrin ń gbìyànjú àti ju ọmọ rẹ̀ nù.
orisiirisii - Orisirisi - July 25, 2019

Arábìnrin ń gbìyànjú àti ju ọmọ rẹ̀ nù.

Won ti mu arabinrin kan ti o n gbiyanju ati ju omo re nu ni aaro oni ni bus stop Ile Epo ni agbegbe Iyana ipaja ni ipinle Eko.

Won ti mu arabinrin naa lo si ago olopaa Ile Epo leyin ti wo ka nibi ti o ti fe ju omo naa sinu gọta ni agbegbe naa. Onsere omo Naijiria, Wale Ilebiyi lo ge aworan isele naa sita.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…