Home Entertainment Mi ò kí ń ṣe lọ́yà àwọn Dakolo – Femi Falana.

Mi ò kí ń ṣe lọ́yà àwọn Dakolo – Femi Falana.

Agba loya ti Naijiria, Femi Falana, ti ni ile ise oun ko lo ma duro fun akorin Timi Dakolo ati iyawo re, Busola.

Loya ajefeto naa so pe oun da si nigba ti molebi naa fi iberu naa nipa iwe-edun naa. Falana ti finipo re han ninu oro naa ni osan ana, leyin ti awon oniroyin n so pe oun ni loya molebi naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…