Home iroyin Ìta tí pa àwọn ọmọ mẹ́fà ní Kaduna.
iroyin - orisiirisii - Orisirisi - July 24, 2019

Ìta tí pa àwọn ọmọ mẹ́fà ní Kaduna.

Aisan ita ti gba emj awon omo mefa, o si ti fi awon miiran si ori idubule aisan ni agbegbe Wusar ni Igabi Local Government Area ni ipinle Kaduna.

Awon mefefa naa wa laaarin awon ogbon ti won ni aisan naa n ba ja ni agbegbe naa ni osu meji seyin.

Igbakeji gomina, Hadiza Balarabe, lo fi idi eri isele naa mule, o si fi ebi si ori awon obi pe won o ki n gbe awon omo won lo fun ajesara(immunization) lati dekun aisan naa.

Bakan naa, o toka si aijeun to tọ ati imototo, ti o n fa iku aitojo fun awon omo ni agbegbe naa. Igbakeji gomina naa ti gba awon obi nimoran pe ki won ma gbe awon omo won lo fun ajesara, ki won si ma se imototo,pe ijoba yoo wa ona ati dekun isele naa ni ojo iwaju.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Arábìnrin ti da omi gbóná lu ọmọ.

Owo olopaati tearabinrin kan ti o da omi gbona lu oju ara omobinrin kekere kan ti n gbe ni…